Kini Itumo oruko re? (Yoruba)

Ile ni ama wô ki a tó somo ni oruko...

Eleyi je owe yoruba ti o jinadenu, yoruba gbagbo ninu oruko eni, oruko abi soni ati oruko amutorunwa. Won gbagbo pé oruko ama roni, oruko a si ma sise pataki ni aiye eda gbogbo. Oruko wo ni o je, tabi oruko wo ni iwo so ara re? ni temi, oruko Mi ni....

Orire!